lekeleke alaso funfun worldwide society
A PLATFORM WHERE HEALTH EDUCATION AND ENLIGhTENMENT IS OUR WATCHWORD,
21/06/2024
ORO NIPA IRAWO ONIKALUKU
Opo Obi loti da igbese aiye omo re ru nipa pe
dandan ise bayi bayi ni o gbodo ko, Olukuluku eda ni
Olohun ti fun ni ise ti yio maa se laye, sugbon latari agidi
ti awa omo Eda Adamo ni koje ki a ni ifura. Oro Olohun
ko le ye omungo Eda sugbon Ologbon eni ni nye, Opo ti o
yeki o lo se ise Briclayer sugbon alakiyesi ko je ki o tete
yan ise ori re layo, Eda ti o baa je omi laye ti o baa nse ise
ina kole ni aluyo laye, eda to si je ina ti o nlo nse ise omi
kole ni ilosiwaju laye. Imo nipa Irawo se koko laye awa
omo eda, eleyi
a jeki eda mo iru igbese aiye ti o le gbe, ohun ti oye ki a
maa se ati ohun ti koye ki ase. Eda ti OIohun da lati ara
omi ti o waa nlo se ise ni ile ise Bread, ki se epe raara
kole ni aluyo laye. Ti abati bi omo Ejeki a gbiyanju ki a to
awon to ni imo nipa Izab wiwo ki won se alaye lori Iru
irawo ti omo naa gbe waa si aiye, iru ise ti ole se. Esu
koni da irin Ajo gbogbo waa ru mo
wa lowo laye. amin
IRAWO ATEGUN
Irawo Ategun je irawo to ni agbara pupo, bi walah batile
po ju fun awon iru irawo yi igbeyin won maa nda pupo,
won nma se orire lehin opolopo walah, oju awon iru eda
bayii maa ni opolopo wahala ni aiye won, oju won ki gbe
ibikan raaraa, ti won baa nse ise kan won atun pa ise naa
ti won a tun gba ibi ise miran lo.
IKILO FUN IRAWO AFEFE
Oro awon eda bayi da gegebi eniti o ngbe kanga ti o waa
de aye kan ti kanga yii ko waa kan omi, okuro ninu kanga
naa, otun bosi ibo miran lati gbe kanga miran, be gege ni
yio se maa gbe kanga yen lo t**i ohun gbogbo ire yio fi
tan mon lowo. Itumo oro yii ni wipe, Gbogbo igbat**i gba ise kan mun mase maa kuro ni ibe ayafi fun idi kan
ISE TO DARA FUN IRAWO ATEGUN
Irawo Ategun gbodo je irawo to lo si school to keko gba
oye (Graduate) idi ni wipe Irawo yii ohun ti won le fi jeun
laye won ni Ise Akowe, iru won ni won maa ndi President,
Governorati bebelo. Awon die ninu ohun ti omo irawo
Ategun le se ni awon wonyi
1. Mass Communication
2. Publisher
3. Alfa
4. Pastor
5. Advitisment
6. Pilot
7. Transportation
Gbogbo ohun ti o baa ti baa ategun mu laye
IKILO PATAKI FUN IRAWO ATEGUN
Irawo Ategun gbodo so ara gidigidi, Irawo Ategun gbodo
je eniti o ntera mo Adura ni gbogbo igba, Ewe ati Egbo
maa ntete je fun irawo Ategun ni idiwon ti won baa tin se
adura daadaa, Irawo ategun gbodo munra si sise Ogun
Isori daadaa, toripe won ki je ki won de ibi giga ti won nlo
laye, Irawo ategun gbodo maa sora ni aye kaye ti won
baa tin se epe pupo toripe Ada awon eda yii lati ara
ategun, asasi ntete maa ja lara opo ninu awon omo
ategun pupo, Egun idile baba nsaba maa nja iran omo
ategun pupo ti ki jeki won tete de ibi giga ti won nlo laye.
Kiyesi, Alakala bi ki won maa je ounje oju oru, tabi ki won
maa ni ajo sepo ni oju oru.
2. IRAWO OMI
Irawo omi lagbara pupo, Asasi ki saba jaa won, sugbon
egun idile baba nsaba maa nba won jaa pupo, Ewe ati
Egbo ki sise lara won rara, Irawo omi ni obinrin iru won ni
won ki gbe ile oko, won ki gbe ile oko toripe okunrin maa
ngbe won ju sile ni, won a maa ni ewa pupo sugbon ogun
promise and fail maa npo fun won pupo, Okunrinmaa nfie si ki won maa yan ale pupo.
IKILO FUN IRAWO OMI
Irawo Omi gbodo teramo Awon nkan isori pupo lati ibere
pepe aiye won, Okunrin won gbodo sora fun isekuse
toripe obinrin maa nda irin ajo won ru pupo toripe won
nma nife si ale yiyan
ISE IRAWO OMI
Die ninu ohun ti Irawo omi le maa se
1.Navey
2.Seaman
3Doctor or Nurse
4Tita Eja tutu
5.Pure water
Gbogbo ohun ti o baa jomo ise omi
3. IRAWO INA
Irawo ina je irawo to ni agbara ju gbogbo irawo lo laye,
Sugbon bi won se buru to Omi ni nma nfa akoba fun
opolopo won. Enia giga ni won pelu laye, Opo ninu won
maa nje alawo pupa, Ewe ati Egbo ntete maa je lara won
bi nkan ti won baa jo lori ina
IKILO FUN IRAWO INA
Irawo naa gbodo sora fun obinrin pupo, bi irawo ina baa
se tan lati fe iyawosile o gbodo se iwadi daadaa toripe bi
okunrin baa je irawo ina ti o baa le baa obinrin ti o je
irawo omi pade, iru won ki gbadun ara won ninu ile, Omi
yii sini yio maa paa ogo ina. Bi won baa ti njo ni ajosepo,
beni omi yio se maa pa ogo ina re.
ISE IRAWO INA
Awon die ninu ise irawo ina
1.Solider
2.Airforce
3.Tailor
4.Hotel
5.Caterer
4. IRAWO IYEPE
Irawo iyepe je irawo ti won nsaba maa ni oju anu pupo,
won je eniti o le soro dada, won ni ogbon pupo, sugbon
iwa igberaga nma nba ise opo won je, won feran iwa imo
toto. Inakuna sin ma nda won lamun pupo
IKILO FUN IRAWO IYEPE
Irawo iyepe gbodo so ara won gidi gidi nipa ina
kuna,Bi suru awon irawo yii se po to be na ni ori
kunkun won se po to nigbati o baa nbinu, sora fun inu
fufu, sora fun iwa tara eni nikan.
ISE IRAWO IYEPE
1.Farmer
2Building construction
3.Musican
4.Teacher
5.Suplier
Etc
AWON EGBO IGI TI O DARA FUN IRAWO RE
1. IRAWO AFEFE
Je eniti yio maa se Adua daadaa, ki osi maa
tan Turari pupo ni igbati o baa nse Adua lowo,
Maa lo Turari Adua dada ni gbogbo igba,
Aseje, Ose, ati Ebu ntete maa nsise lara iru
irawo yii nidiwon ti won baa nti nse adua ki
won to lo3.
IRAWO INA
Irawo ina gbodo sora fun wiwe ose ni gbogbo
igba, Ohun ti o dara fun iru irawo yii naa ni Ki
won maa lo Ebu ti a jo.. Ebu ni o nsaba maa
sise pupo fun won ju gbogbo ogun miran lo,
Awon Ogun miran naa maa nsise fun won
sugbon ko dabi ki won lo Ebu
4. IRAWO IYEPE
Irawo yii gbodo maa se Sara Daadaa, ki won
maa fon awon nkan jije si ile fun awon eda ti
won nse aiye iyepe, Ose Dudu ati Aseje dara
pupo fun won
AWON IRAWO OJO IBI
1.January 20 si February 18 Irawo Afefe
2.February 19 si March 20 irawo Omi
3.March 21 si April 19 Irawo Ina
4.April 20 si May 20 Irawo ile
5.May 21 si June 20 Irawo Afefe
6.June 21 si July 22 Irawo omi
7.July 23 si August 22 irawo ina
8.August 23 si September 22 irawo ile
9.September 23 si October 22 irawo afefe
10 October 23 si November 21 irawo omi
11 Novermber 22 si December 21 irawo ina
12 December 22 si Jnuary 19 irawo ile
2. IRAWO OMI
Ki won je iru Eda ti o nlo nkan ti won fi omi
pipe, gegebi Hantu mumu, Obe Aseje tabi ki
won maa we ose dudu. Ebu Jijo ki sise lara
won, bi won baa fi one million se ebu fun iru
won kole ri one naira ni ibe.
17/02/2024
Oríki para llamar a Ọrúnmìlà
Èlà ro wá 3x
O dúndún ro wà 3x
Tèté ro wà 3x
Omi tutu ro wá 3x
Orúnmìlà ìwọ lo ro sè ‘kerin won.
Ò ní ení bá pè ó bí o re apá kùnkun,
Ìlà méjì òsà
Tí o bá re ibi ogún odún
Tí o bá re ibi ogbòn osù
Ifá to ba nbe n’ìko àwósí,
Kí o ro wá
Bí o bá nbe ní ìdòròmù àwísè,
Kí o ro wá
Bí o bá nbe ní ìwònràn,
Agbede méjì ayé òun òrun,
Ibi tí ojú mó ire ti nmó wá ilé ayé,
Kí o ro wá
Traducción...
Èlà baja 3x
Ọdúndún baja 3x
Tèté baja 3x
El agua fría baja 3x
Ọrúnmìlà eres la cuarta persona.
Dijiste quien te invite, aunque estés en apá kùnkun
Las dos líneas de deidades.
Incluso si te has ido por veinte años
Incluso si te has ido por treinta meses
Ifá si estás en ìko àwósí, baja.
Ifá si estás en ìdòròmù àwísè, baja.
Si estás en ìwònràn,
El espacio entre el cielo y la tierra,
Donde el buen día amanece sobre la tierra, desciende
*if you have any type of this issues, Whatsapp me or call 0 810 870 4089, tayeshe agbaye
*1. Hepat**is (Aisan jedo jedo)*
*2. Liver problem (Aisan Edo)*
*3. Kidney problem (Aisan kidinrin)*
*4. Stroke (Ropa rose)*
*5. Autism (Aida pe omo)*
*6. Arthritis (Awoka)*
*7. Rheumatism (San gun San gun abi lagun lagun)*
*8. Heart problem (Aisan okan)*
*9. Hypertension (Ifun pa giga)*
*10. High cholesterol (Ki ora po ju ni ara)*
*11. Obesity (Ti to bi ju)*
*12. Cancer (Aisan jejere)*
*13. Paralysis (Ki aye kan la ku abi ti ko si se mo)*
*14. Epilepsy (Warapa)*
*15. Appendix (Afikun)*
*16. Bone disease (Aisan inu egun)*
*17. Tummy fat (Ikun ti to bi)*
*18. Brain tumour (Tumor bi opolo)*
*ETC (Ati bebe loo) 🌹🌹🌹*
28/04/2023
26/04/2023
Osun agbewa ooo,
Back to sender, ejo ooye
Ogun lakaye eru e bami
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Telephone
Website
Address
Sango Otta
112104